Lyrics: SQ Drk - Won Gbe ft SugarBanah

We are excited to announce the release of the lyrics to SQ Drk’s new studio record tagged, “Won Gbe” This highly anticipated album showcases “SQ Drk’s ” incredible talent and unique style. With the support of SugarBanah, the album is set to make waves in the music industry.

 Lyrics:

Ummmmh         Sugarbanah

Yeah, SQ lọ́pá beat, DRK Whatyoudo?, hahaha, bàbá yín

Chorus:

Ọmọ tó gbà payroll, ló yẹ kó ṣe parole

Ó gbà owó Wells-Fargo, ó lọ fẹ́ rà aṣọ Jago

Wọ́n gbé l’adúgbò yìí (wọ́n gbé), kò sí ọ̀run l’adúgbò yìí (wọ́n gbé)

àsòmù adúgbò yìí ( wọn gbé)

atenu adugbo yii (gbogbo wọn gbé)

Ọmọ mi gba  Lambo, ó ra ilé ní Magodo

Ìgàrà Shina Rambo, ó súnmọ́ Davido

A ní wọ́n gbé l’adúgbò yìí (wọ́n gbé), 

kò sí ọ̀run l’adúgbò yìí (wọ́n gbé)

Òlòṣò adúgbò yìí (wọ́n gbé), 

àsòmù adúgbò yìí (gbogbo wọn gbé)

Verse 1:

DRK mo gbọ́pé, mo set parole, mo pé ago Bọ́lánlé, mo shenk Carol

Ojọ́ bí ìdàn, búh grace là ń lọ, Ìyàbọ̀ tí o jó, ìrán ló ń wò

Níbo? Ládúgbò mi, tí ń ti yọ, gbogbo ọmọge láti jẹ bí opìró

Bówo jẹ́ bí Àpá Ọmọ Ọba, wọ́n ò rí rò,

Ọpẹ́lọ́pẹ̀ Wells-Fargo

Kí payroll tó tẹ̀lẹ̀ báyìí, mò ti pé Rahman Jago

High fashion, Mayemi gàn, nínú Lambo

Ṣé o ní ìdí ìkà? Pàdé mi ní Magodo

Àwọn ọmọge olóyàn méjì (wọ́n gbé)

Sugarbanah, fẹrán booty, kilódè?

Steady Dorime, holiday ke? Yẹ̀pà! Gbogbo àwọn ọmọ adúgbò Kelegbe (ye)

Check my steeze, mó gbé ọmọge méjì

Bàbá yín lónìí parole Ehn 

Baby, lamba pọ̀, tó kún ọ́wó̩, tó kún ẹnu

Fi gbèdù kọ́wọ̀ l’ọbẹ̀ lọ o baby

Sugar gbé sókè

Chorus:

Ọmọ tó gbà payroll, ló yẹ kó ṣe parole(Bàbá yín)

Ó gbà owó Wells-Fargo, ó lọ fẹ́ rà aṣọ Jago(Omo ologo daaya) ….. Yeeh 

Wọ́n gbé l’adúgbò yìí (wọ́n gbé), kò sí ọ̀run l’adúgbò yìí (wọ́n gbé)

àsòmù adúgbò yìí ( wọn gbé)

atenu adugbo yii (gbogbo wọn gbé)

Ọmọ mi ra Lambo, ó ra ilé ní Magodo

Ìgàrà Shina Rambo, ó súnmọ́ Davido

A ní wọ́n gbé l’adúgbò yìí (wọ́n gbé), 

kò sí ọ̀run l’adúgbò yìí (wọ́n gbé)

Òlòṣò adúgbò yìí (wọ́n gbé), 

àsòmù adúgbò yìí (gbogbo wọn gbé)

Verse 2: 

Wọ́n kú, wọ́n gbé, wọ́n dàrán — bàbá yín dé o, jẹ́ kó mọ̀

Jàíyé bí King Solomon, kó gbogbo ọmọ wọ́n ní Quilox

Ọmọ Ọba wò Amapiano ìkà, tó kún bọ́bọ́

Àlàyé, wọ́n máa fi ẹ lógbà, tó bá lọ ń fọ́

Ah! London–Naija oo, kí ló ń bọ̀?

Virgin Atlantic ló bàbọ̀

Versace sneakers, Gucci top, First Class mò ṣá o — jẹ́ kó mọ̀

Màgà ló ń dá owó, ìdàn ló ń biza

Ẹ má wò panpa lọ́wọ́!

Sòkòtò Jago, Nike fìlà, bàtà of thug **

Outro

SQ Whatyoudo?,

Bàbá yín tí kò ní chest and lungs

Ọmọ òlógò, dááyá —

They don’t know

(Holumide on the mix)

Wọ́n ò dá mọ̀ Jiooo Omoooh

Post a Comment

0 Comments